IPADE ELERE-IDARAYA




IPADE ELERE-IDARAYA
Awo n pe awo! Tilu tifon!
Awon akopa n figa gbaga,
Won n sare ninu ogba alawo eweko yii,
Bi ebora elere ti n pora lati okankan,
Won n korin. Won n wo won, mo n gbo ninu iyaleni mi
Awon omode ti n yin epo wara.

A SPORTS MEET
Colours call on colours! Drums and rump roll!
The participants in the corporeal performance
March past fast into the grinning green bowl,
Like fleeting ghosts glimpsed from a distance,
Singing. Staring, I hear in my rear crumbs
Of laughter of kids exploding yoghurt bombs.


Translated from A SPORT MEET BY SEGUN ADEKOYA in HERE & THERE, 2012.

Labels: , , , , , , ,