ODIDERE TO RO!

E jeki a fi ti odidere to ro,
Eye ti ki ku si oko iwa je,
A mu lo, a mu bo,
Ni owo n na enu!
Odidere!

Ka fi ti Odidere to ro,
Ki a ma baa sirin,
Ki a fi to Odidere to ro,
Ka lo layo, ka ma bo layo,
Ka fi ti Odidere to ro,
Ka ma ri se,
Ka fi ti Odidere to ro,
Ka bode pade,
Ka fi ti Odidere to ro,
Ki ani to ati ani se ku je ti wa!

Odidere,
A fi ti e to ro ni,
Ki oro wa le dayo,
Ki igba le san wa so wo,
Ki aseyori o je ti wa,
Odidere ki ku si oko iwa je o!

Labels: , , , , , , , , ,